- This event has passed.
Abosede Ipadeola: Philosophizing in Yorùbá: Exploring a People’s Weltanschauung (Lecture)
June 26, 2025 @ 14:00 – 16:00
Part of the Lecture Series: Philosophizing in African Languages
Click for more information:
Abstract
Yoruba is the language and culture of a people primarily found in Nigeria, Benin, Togo, Sierra Leone, Cuba, and Brazil. Their philosophical ideas prominently feature in their culture, language, and traditions. In this lecture, I will explore how the Yoruba people have conceptualized existence, morality, knowledge, and governance. Additionally, I will analyze stories, poems, proverbs, and literary texts from the Yoruba tradition, including the Ifa literary corpus, that provide valuable insights into how the Yoruba have engaged with fundamental philosophical questions over the centuries.
Ìdánílẹ̀kọ́ ní ṣókí
Yorùbá jẹ́ èdè abínibí àti àṣà àwọn ẹ̀yà tí ó ń gbé àwọn orílẹ̀-èdè bí i Nàìjíríà, Bìnì, Tógò, Ilẹ̀ Sàró, Kúbà, àti, Ilẹ̀ Bùràsílì. Àwọn èrò wọn nípa Èkọ́ Ìfẹ́-Ọgbọ́n, tí a mọ̀ sí Filọ́sọ́fì, ni a lè bá pàdé nínú àṣà, èdè àti ìṣe àwọ̀n ẹ̀yà Yorùbá. Nínú ìkọ́nílẹ̀kọ́ yìí, n ó ṣàfihàn ìwòye àwọn Yorùbá nípa ìwàláàyè, ìwùwàsí, ìmọ̀, àti ìṣèlú. Bákan náà, n ó ṣe àyẹ̀wò àwọn ìtàn, ewì, òwe, àti àwọn ìwé àtẹnudẹ́nu, pàápàá àwọn odù ifá, tí ó ń ṣàfihàn bí àwọn Yorùbá ṣe ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ògbóǹtarìgì ìbéèrè tó ní í ṣe pẹ̀lú Èkọ́ Ìfẹ́-Ọgbọ́n láti ayébáyé.

